Return to Video

MasterFirefoxOS.com: Firefox Browser

  • 0:07 - 0:12
    Ìṣawarí Firefox ni ọ̀nà ìyára tí ó rọrùn tí ó ní ààbò láti gba èyí tí ó dárajù ní wẹ́ẹ̀bù.
  • 0:13 - 0:17
    Àwọn oníbárà rẹ lè ṣàyẹwò ojúlé wẹ́ẹ̀bụ̀ wọn láti àṣàfihàn ilé
  • 0:18 - 0:20
    tàbí lo pẹpẹ wíwá láti kànsí àwọn ojúlé wẹ́ẹ̀bù,
  • 0:21 - 0:24
    láti ṣe ìwarí àti wo ìtàn ìṣawarí
  • 0:24 - 0:28
    àti àwọn táàbù jẹ́kí ọ̀pọ̀ iṣẹ́ nípa ọ̀pọ̀ ìṣawarí àwọn ojú ewé lẹ́ẹ́kànṣo.
  • 0:29 - 0:31
    Mozilla ni ó ṣe gbogbo rẹ̀,
  • 0:31 - 0:35
    àwùjọ àgbaayé tí ó farajìn láti ri pé ojúlé wẹ́ẹ̀bù wà ní ṣíṣí àti aṣẹ́wọ̀ fún gbogbo ènìyàn.
Title:
MasterFirefoxOS.com: Firefox Browser
Video Language:
English
Duration:
0:39

Yoruba subtitles

Revisions