0:00:07.000,0:00:12.290 Ìṣawarí Firefox ni ọ̀nà ìyára tí ó rọrùn tí ó ní ààbò láti gba èyí tí ó dárajù ní wẹ́ẹ̀bù. 0:00:13.200,0:00:17.300 Àwọn oníbárà rẹ lè ṣàyẹwò ojúlé wẹ́ẹ̀bụ̀ wọn láti àṣàfihàn ilé 0:00:17.680,0:00:20.300 tàbí lo pẹpẹ wíwá láti kànsí àwọn ojúlé wẹ́ẹ̀bù, 0:00:20.550,0:00:24.310 láti ṣe ìwarí àti wo ìtàn ìṣawarí 0:00:24.440,0:00:28.180 àti àwọn táàbù jẹ́kí ọ̀pọ̀ iṣẹ́ nípa ọ̀pọ̀ ìṣawarí àwọn ojú ewé lẹ́ẹ́kànṣo. 0:00:29.080,0:00:30.600 Mozilla ni ó ṣe gbogbo rẹ̀, 0:00:30.840,0:00:35.040 àwùjọ àgbaayé tí ó farajìn láti ri pé ojúlé wẹ́ẹ̀bù wà ní ṣíṣí àti aṣẹ́wọ̀ fún gbogbo ènìyàn.