Ìṣawarí Firefox ni ọ̀nà ìyára tí ó rọrùn tí ó ní ààbò láti gba èyí tí ó dárajù ní wẹ́ẹ̀bù. Àwọn oníbárà rẹ lè ṣàyẹwò ojúlé wẹ́ẹ̀bụ̀ wọn láti àṣàfihàn ilé tàbí lo pẹpẹ wíwá láti kànsí àwọn ojúlé wẹ́ẹ̀bù, láti ṣe ìwarí àti wo ìtàn ìṣawarí àti àwọn táàbù jẹ́kí ọ̀pọ̀ iṣẹ́ nípa ọ̀pọ̀ ìṣawarí àwọn ojú ewé lẹ́ẹ́kànṣo. Mozilla ni ó ṣe gbogbo rẹ̀, àwùjọ àgbaayé tí ó farajìn láti ri pé ojúlé wẹ́ẹ̀bù wà ní ṣíṣí àti aṣẹ́wọ̀ fún gbogbo ènìyàn.