1 00:00:07,000 --> 00:00:12,290 Ìṣawarí Firefox ni ọ̀nà ìyára tí ó rọrùn tí ó ní ààbò láti gba èyí tí ó dárajù ní wẹ́ẹ̀bù. 2 00:00:13,200 --> 00:00:17,300 Àwọn oníbárà rẹ lè ṣàyẹwò ojúlé wẹ́ẹ̀bụ̀ wọn láti àṣàfihàn ilé 3 00:00:17,680 --> 00:00:20,300 tàbí lo pẹpẹ wíwá láti kànsí àwọn ojúlé wẹ́ẹ̀bù, 4 00:00:20,550 --> 00:00:24,310 láti ṣe ìwarí àti wo ìtàn ìṣawarí 5 00:00:24,440 --> 00:00:28,180 àti àwọn táàbù jẹ́kí ọ̀pọ̀ iṣẹ́ nípa ọ̀pọ̀ ìṣawarí àwọn ojú ewé lẹ́ẹ́kànṣo. 6 00:00:29,080 --> 00:00:30,600 Mozilla ni ó ṣe gbogbo rẹ̀, 7 00:00:30,840 --> 00:00:35,040 àwùjọ àgbaayé tí ó farajìn láti ri pé ojúlé wẹ́ẹ̀bù wà ní ṣíṣí àti aṣẹ́wọ̀ fún gbogbo ènìyàn.