Return to Video

NatureNow: Greta Thunberg and George Monbiot make short film on the climate crisis

 • 0:02 - 0:04
  Ọ̀rọ̀ ńlá rèé o
 • 0:04 - 0:07
  Orúkọ mi ni Greta Thunberg
 • 0:07 - 0:10
  Ní àkókò wa yìí, ọ̀pọ̀ nǹkan ti bẹ̀rẹ̀ sí í pa run
 • 0:11 - 0:14
  Afẹ́fẹ́ àti àyíká wa ń bà jẹ́
 • 0:14 - 0:18
  Àwọn ọmọdé bíi tèmi pa ẹ̀kọ́ ìwé tì láti wọdé.
 • 0:19 - 0:21
  A ṣì lè tún ohun tó ti bà jẹ́ ṣe.
 • 0:21 - 0:23
  Ìwọ náà lè tún un ṣe.
 • 0:23 - 0:27
  Tá ò bá fẹ́ kí aráyé pa run, a gbọ́dọ̀ jáwọ́ nínú sísun epo rọ̀bì, àmọ́ ìyẹn nìkan ò tó.
 • 0:27 - 0:30
  Ọ̀pọ̀ àbá ni àwọn èèyàn ti dá, àmọ́ ojútùú kan wà fún wa.
 • 0:30 - 0:33
  wa
 • 0:33 - 0:35
  Ẹ jẹ́ kí ọ̀rẹ́ mi George ṣàlàyé.
 • 0:36 - 0:38
  Ẹ̀rọ ńlá kan wà tó máa ń fa èròjà carbon kúrò nínú afẹ́fẹ́, owó rẹ̀ ò pọ̀, ó sì máa ń tún
 • 0:38 - 0:43
  ara rẹ̀ ṣe
 • 0:43 - 0:44
  Òun là ń pè ní ... igi.
 • 0:44 - 0:46
  Igi jẹ́ ọ̀kan lára ohun tó dá a jù láti fi tún afẹ́fẹ́ ṣe.
 • 0:47 - 0:48
  Àwọn igi ẹ̀gbà, koríko tó ti kú, igbó ńlá, ilẹ̀ pọ̀tọ̀pọ́tọ́, ìsàlẹ̀ òkun, igbó tí koríko bò, irà, òkìtì iyùn inú òkun
 • 0:48 - 0:49
  gbogbo wọn ló ń bá wa fa èròjà carbon kúrò nínú afẹ́fẹ́
 • 0:49 - 0:54
  Igbó fúnra rẹ̀ ní ohun tó lè bá wa tún afẹ́fẹ́ tó ti bà jẹ́ ṣe.
 • 0:54 - 0:57
  Tá a bá jẹ́ kí igi àti afẹ́fẹ́ tún àyíká ṣe, àá rí ìyàtọ̀ ńlá.
 • 0:57 - 0:59
  Ìyẹn dáa, àbí bẹ́ẹ̀kọ́?
 • 0:59 - 1:03
  Kí ìyẹn tó lè ṣẹlẹ̀, àfi ká fi epo rọ̀bì sàyẹ̀ rẹ̀ nínú ilẹ̀.
 • 1:03 - 1:08
  Àmọ́ ohun to yani lẹ́nu ni pé ... a ò ṣe ohun tó yẹ ká ṣe
 • 1:09 - 1:12
  Owó tí à ń ná lórí ìrànwọ́ fún wíwa epo rọ̀bì fi ìlọ́po ẹgbẹ̀rún ju owó tá a fi ń wá
 • 1:12 - 1:14
  ojútùú lọ.
 • 1:14 - 1:18
  Ìdá méjì nínú ọgọ́rùn-ún péré là ń ná
 • 1:20 - 1:22
  nínú gbogbo owó ìrànwọ́ láti fi wá ojútùú sí afẹ́fẹ́ tó ń bà jẹ́.
 • 1:22 - 1:24
 • 1:26 - 1:31
  Owó ẹ, owó orí ẹ àti èyí tí ò ń fi pa mọ́ wà lára owó yìí.
 • 1:31 - 1:33
  Ibi tí ọ̀rọ̀ wa ni pé ìsinsìnyí gan-an la nílò igi, afẹ́fẹ́ àti àyíká wa jù
 • 1:33 - 1:35
  àmọ́ ńṣe ni àwọn nǹkan yìí ń bà jẹ́ lọ́nà tó yára kánkán
 • 1:35 - 1:39
  Ó tó igba (200) ẹ̀dá abẹ̀mí tó ń pa run lójoojúmọ́
 • 1:39 - 1:41
  Òkìtì yìnyín ńlá tó wà nípẹ̀kun ayé tí fẹ́rẹ̀ẹ́ yọ́ tán
 • 1:41 - 1:43
  Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹranko inú igbó ti kú tán
 • 1:44 - 1:45
  Ọ̀pọ̀lọ̀pọ ilẹ̀ ló ti bà jẹ́.
 • 1:45 - 1:47
  Kí ló yẹ ká ṣe?
 • 1:47 - 1:50
  Kí ni ìwọ lè ṣe?
 • 1:50 - 1:54
  Kò le rárá ... a ní láti dáàbò ohun tó ń bà jẹ́, ká tún un ṣe, ká sì fowó ṣètìlẹ́yìn.
 • 1:54 - 1:57
  Dáàbò bò ó.
 • 1:57 - 1:59
  Iye àwọn igbó tó wà nílẹ̀ olóoru tí à ń gé
 • 1:59 - 2:01
  láàárín ìṣẹ́jú kan tó ọgbọ̀n (30) pápá bọ́ọ̀lù.
 • 2:01 - 2:03
  Àwọn igbó yìí ń ṣe wá lóore, ó yẹ ká dáàbò bò wọ́n
 • 2:03 - 2:04
  Tún un ṣe
 • 2:04 - 2:05
  Apá tó pọ̀ jù lọ láyé yìí ti bà jẹ́.
 • 2:05 - 2:06
  Àmọ́ ó lè sọ ara rẹ̀ dọ̀tun
 • 2:06 - 2:07
  àwa náà lè ṣèrànwọ́ láti sọ àyíka wa di ọ̀tun
 • 2:07 - 2:09
 • 2:09 - 2:10
  Owó.
 • 2:10 - 2:11
  A ní láti jáwọ́ nínú nínáwó sórí ohun tó ń ba àyíká jẹ́
 • 2:11 - 2:13
  ká náwó sórí ohun tó lè tú un ṣe.
 • 2:13 - 2:16
  kò jù bẹ́ẹ̀ lọ.
 • 2:16 - 2:19
  Dáàbò bò ó, tún un ṣe, nawo.
 • 2:19 - 2:21
  A lè ṣe bẹ́ẹ̀ kárí ayé
 • 2:21 - 2:22
  Ọ̀pọ̀ èèyàn ti ń lo igi, afẹ́fẹ́, àti àyíká láti wá ojútùú sọ́rọ̀ yìí
 • 2:22 - 2:25
  Gbogbo wa la gbọ́dọ̀ pawọ́ pọ̀ ṣe é.
 • 2:25 - 2:27
  Ìwọ náà lè kópa ńbẹ̀.
 • 2:27 - 2:30
  Dìbò fún àwọn tó ń gbèjà àyíká wa.
 • 2:31 - 2:32
  Pín fídíò yìí kiri.
 • 2:33 - 2:36
  Sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀.
 • 2:36 - 2:38
  Kárí ayé, àwọn èèyàn tí ò fẹ́ kí àyíká wa bà jẹ́ ń wọ́de lórí ọ̀rọ̀ yìí.
 • 2:39 - 2:41
  Tẹ̀ lé wọn!
 • 2:41 - 2:42
  Kò sóhun tó gbé.
 • 2:42 - 2:43
  Ohun tó o bá ṣe ò gbé.
Title:
NatureNow: Greta Thunberg and George Monbiot make short film on the climate crisis
Description:

Environmental activists Greta Thunberg and George Monbiot have helped produce a short film highlighting the need to protect, restore and use nature to tackle the climate crisis.

Living ecosystems like forests, mangroves, swamps and seabeds can pull enormous quantities of carbon from the air and store them safely, but natural climate solutions currently receive only 2% of the funding spent on cutting emissions.

The film’s director, Tom Mustill of Gripping Films, said: 'We tried to make the film have the tiniest environmental impact possible. We took trains to Sweden to interview Greta, charged our hybrid car at George’s house, used green energy to power the edit and recycled archive footage rather than shooting new.'

#naturenow #climatecrisis #gretathunberg

CREDITS

Narrators: Greta Thunberg & George Monbiot
Director: Tom Mustill
Producer: Triangle Monday
DoP & Editor: Fergus Dingle
Sound: Shaman Media
GFX: Paraic Mcgloughlin
Online: Bram De Jonghe
Picture Post: Special Treats Productions
Mix: Mcasso Music
Audio Post: Tom Martin
NCS Guidance: Charlie Lat
Music: Rone / InFiné Music

The Independent film by Gripping Films(Tom Mustill) was supported by:
Conservation International
Food and Land Use Coalition
Gower St

With guidance from
Nature4Climate

Natural Climate Solutions

www.grippingfilms.com

FIND OUT MORE:
#naturenow
www.naturalclimate.solutions

more » « less
Video Language:
English
Team:
Amplifying Voices
Project:
Environment and Climate Change
Duration:
03:41

Yoruba subtitles

Revisions Compare revisions