NatureNow: Greta Thunberg and George Monbiot make short film on the climate crisis
-
0:02 - 0:04Ọ̀rọ̀ ńlá rèé o
-
0:04 - 0:07Orúkọ mi ni Greta Thunberg
-
0:07 - 0:10Ní àkókò wa yìí, ọ̀pọ̀ nǹkan ti bẹ̀rẹ̀ sí í pa run
-
0:11 - 0:14Afẹ́fẹ́ àti àyíká wa ń bà jẹ́
-
0:14 - 0:18Àwọn ọmọdé bíi tèmi pa ẹ̀kọ́ ìwé tì láti wọdé.
-
0:19 - 0:21A ṣì lè tún ohun tó ti bà jẹ́ ṣe.
-
0:21 - 0:23Ìwọ náà lè tún un ṣe.
-
0:23 - 0:27Tá ò bá fẹ́ kí aráyé pa run, a gbọ́dọ̀ jáwọ́ nínú sísun epo rọ̀bì, àmọ́ ìyẹn nìkan ò tó.
-
0:27 - 0:30Ọ̀pọ̀ àbá ni àwọn èèyàn ti dá, àmọ́ ojútùú kan wà fún wa.
-
0:30 - 0:33wa
-
0:33 - 0:35Ẹ jẹ́ kí ọ̀rẹ́ mi George ṣàlàyé.
-
0:36 - 0:38Ẹ̀rọ ńlá kan wà tó máa ń fa èròjà carbon kúrò nínú afẹ́fẹ́, owó rẹ̀ ò pọ̀, ó sì máa ń tún
-
0:38 - 0:43ara rẹ̀ ṣe
-
0:43 - 0:44Òun là ń pè ní ... igi.
-
0:44 - 0:46Igi jẹ́ ọ̀kan lára ohun tó dá a jù láti fi tún afẹ́fẹ́ ṣe.
-
0:47 - 0:48Àwọn igi ẹ̀gbà, koríko tó ti kú, igbó ńlá, ilẹ̀ pọ̀tọ̀pọ́tọ́, ìsàlẹ̀ òkun, igbó tí koríko bò, irà, òkìtì iyùn inú òkun
-
0:48 - 0:49gbogbo wọn ló ń bá wa fa èròjà carbon kúrò nínú afẹ́fẹ́
-
0:49 - 0:54Igbó fúnra rẹ̀ ní ohun tó lè bá wa tún afẹ́fẹ́ tó ti bà jẹ́ ṣe.
-
0:54 - 0:57Tá a bá jẹ́ kí igi àti afẹ́fẹ́ tún àyíká ṣe, àá rí ìyàtọ̀ ńlá.
-
0:57 - 0:59Ìyẹn dáa, àbí bẹ́ẹ̀kọ́?
-
0:59 - 1:03Kí ìyẹn tó lè ṣẹlẹ̀, àfi ká fi epo rọ̀bì sàyẹ̀ rẹ̀ nínú ilẹ̀.
-
1:03 - 1:08Àmọ́ ohun to yani lẹ́nu ni pé ... a ò ṣe ohun tó yẹ ká ṣe
-
1:09 - 1:12Owó tí à ń ná lórí ìrànwọ́ fún wíwa epo rọ̀bì fi ìlọ́po ẹgbẹ̀rún ju owó tá a fi ń wá
-
1:12 - 1:14ojútùú lọ.
-
1:14 - 1:18Ìdá méjì nínú ọgọ́rùn-ún péré là ń ná
-
1:20 - 1:22nínú gbogbo owó ìrànwọ́ láti fi wá ojútùú sí afẹ́fẹ́ tó ń bà jẹ́.
-
1:22 - 1:24
-
1:26 - 1:31Owó ẹ, owó orí ẹ àti èyí tí ò ń fi pa mọ́ wà lára owó yìí.
-
1:31 - 1:33Ibi tí ọ̀rọ̀ wa ni pé ìsinsìnyí gan-an la nílò igi, afẹ́fẹ́ àti àyíká wa jù
-
1:33 - 1:35àmọ́ ńṣe ni àwọn nǹkan yìí ń bà jẹ́ lọ́nà tó yára kánkán
-
1:35 - 1:39Ó tó igba (200) ẹ̀dá abẹ̀mí tó ń pa run lójoojúmọ́
-
1:39 - 1:41Òkìtì yìnyín ńlá tó wà nípẹ̀kun ayé tí fẹ́rẹ̀ẹ́ yọ́ tán
-
1:41 - 1:43Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹranko inú igbó ti kú tán
-
1:44 - 1:45Ọ̀pọ̀lọ̀pọ ilẹ̀ ló ti bà jẹ́.
-
1:45 - 1:47Kí ló yẹ ká ṣe?
-
1:47 - 1:50Kí ni ìwọ lè ṣe?
-
1:50 - 1:54Kò le rárá ... a ní láti dáàbò ohun tó ń bà jẹ́, ká tún un ṣe, ká sì fowó ṣètìlẹ́yìn.
-
1:54 - 1:57Dáàbò bò ó.
-
1:57 - 1:59Iye àwọn igbó tó wà nílẹ̀ olóoru tí à ń gé
-
1:59 - 2:01láàárín ìṣẹ́jú kan tó ọgbọ̀n (30) pápá bọ́ọ̀lù.
-
2:01 - 2:03Àwọn igbó yìí ń ṣe wá lóore, ó yẹ ká dáàbò bò wọ́n
-
2:03 - 2:04Tún un ṣe
-
2:04 - 2:05Apá tó pọ̀ jù lọ láyé yìí ti bà jẹ́.
-
2:05 - 2:06Àmọ́ ó lè sọ ara rẹ̀ dọ̀tun
-
2:06 - 2:07àwa náà lè ṣèrànwọ́ láti sọ àyíka wa di ọ̀tun
-
2:07 - 2:09
-
2:09 - 2:10Owó.
-
2:10 - 2:11A ní láti jáwọ́ nínú nínáwó sórí ohun tó ń ba àyíká jẹ́
-
2:11 - 2:13ká náwó sórí ohun tó lè tú un ṣe.
-
2:13 - 2:16kò jù bẹ́ẹ̀ lọ.
-
2:16 - 2:19Dáàbò bò ó, tún un ṣe, nawo.
-
2:19 - 2:21A lè ṣe bẹ́ẹ̀ kárí ayé
-
2:21 - 2:22Ọ̀pọ̀ èèyàn ti ń lo igi, afẹ́fẹ́, àti àyíká láti wá ojútùú sọ́rọ̀ yìí
-
2:22 - 2:25Gbogbo wa la gbọ́dọ̀ pawọ́ pọ̀ ṣe é.
-
2:25 - 2:27Ìwọ náà lè kópa ńbẹ̀.
-
2:27 - 2:30Dìbò fún àwọn tó ń gbèjà àyíká wa.
-
2:31 - 2:32Pín fídíò yìí kiri.
-
2:33 - 2:36Sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀.
-
2:36 - 2:38Kárí ayé, àwọn èèyàn tí ò fẹ́ kí àyíká wa bà jẹ́ ń wọ́de lórí ọ̀rọ̀ yìí.
-
2:39 - 2:41Tẹ̀ lé wọn!
-
2:41 - 2:42Kò sóhun tó gbé.
-
2:42 - 2:43Ohun tó o bá ṣe ò gbé.
- Title:
- NatureNow: Greta Thunberg and George Monbiot make short film on the climate crisis
- Description:
-
Environmental activists Greta Thunberg and George Monbiot have helped produce a short film highlighting the need to protect, restore and use nature to tackle the climate crisis.
Living ecosystems like forests, mangroves, swamps and seabeds can pull enormous quantities of carbon from the air and store them safely, but natural climate solutions currently receive only 2% of the funding spent on cutting emissions.
The film’s director, Tom Mustill of Gripping Films, said: 'We tried to make the film have the tiniest environmental impact possible. We took trains to Sweden to interview Greta, charged our hybrid car at George’s house, used green energy to power the edit and recycled archive footage rather than shooting new.'
#naturenow #climatecrisis #gretathunberg
CREDITS
Narrators: Greta Thunberg & George Monbiot
Director: Tom Mustill
Producer: Triangle Monday
DoP & Editor: Fergus Dingle
Sound: Shaman Media
GFX: Paraic Mcgloughlin
Online: Bram De Jonghe
Picture Post: Special Treats Productions
Mix: Mcasso Music
Audio Post: Tom Martin
NCS Guidance: Charlie Lat
Music: Rone / InFiné MusicThe Independent film by Gripping Films(Tom Mustill) was supported by:
Conservation International
Food and Land Use Coalition
Gower StWith guidance from
Nature4ClimateNatural Climate Solutions
www.grippingfilms.com
FIND OUT MORE:
#naturenow
www.naturalclimate.solutions - Video Language:
- English
- Team:
- Amplifying Voices
- Project:
- Environment and Climate Change
- Duration:
- 03:41