Firefox OS jẹ́kí àwọn oníbárà rẹ gba gbogbo àwọn àfetigbọ́ tí wọ́n fẹ́ lóri irìn
gbogbo rẹ̀ lóri ohun èlò kan
pẹ̀lú títẹ̀ lẹ́ẹ̀kan lórí orin àwòrán aṣàmì,
wọ́n á rí gbogbo àwọn ohùn orin ní́ ibìkan.
Wọ́n lè ṣe ìṣawarí àkójọ wọn ní ònkọrin tàbí àwo orin
wá àwọn orin ní àpotí wíwá
ṣèdíwọ̀n àwọn orin
pín wọn
àti ìṣẹ̀dá àtòkọ orin ààyo wọn
ìṣafilọ́lẹ̀ rédíò FM síwà
Àwọn oníbárà rẹ lèrí ibùdó tí wọ́n fẹ́ yísí
tàbí kí Firefox OS wa fún wọn.