1 00:00:07,260 --> 00:00:13,614 Mímú, ìfipamọ́ àti pípín àwọn fọ́tò àti f́idíò, kòle rọrùn ju lílo Firefox OS kámẹ́rà àti àwọn gbàgede ìṣafilọ́lẹ̀. 2 00:00:14,140 --> 00:00:17,000 HDR jẹ́kí àwọn oníbárà rẹ ya àwọn àwòrán tí ó rẹwà 3 00:00:17,780 --> 00:00:21,640 wọ́n sì le lo ìlo àkókò láti ya àwòrán wọn àti ti àwọn ọ̀rẹ́. 4 00:00:22,860 --> 00:00:26,680 Gbogbo àwọn fọ́tò wọn hàn ni ́aládàṣe ní gbàgede fún ìṣawarí àti ìṣàtúnṣe. 5 00:00:30,300 --> 00:00:33,300 Wọ́n lè dán àwọn asẹ́ àrà wò 6 00:00:38,540 --> 00:00:40,080 ṣèréjẹ àwọn fọ́tò wọn 7 00:00:45,520 --> 00:00:48,987 yí àwọn ààtò ìrí 8 00:00:53,860 --> 00:00:56,100 àti àwọn ọ̀pọ̀ ọ̀nà láti pín àwọn fọ́tò wọn, 9 00:00:56,100 --> 00:01:01,060 gbogbo àbùdá kámẹ́rà àti gbàgede fọ́tò ni yóò mú gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ àti mọ̀lẹ̀bí rẹ́rìn.