1 00:00:01,560 --> 00:00:04,135 Ọ̀rọ̀ ńlá rèé o 2 00:00:04,375 --> 00:00:06,651 Orúkọ mi ni Greta Thunberg 3 00:00:06,852 --> 00:00:10,212 Ní àkókò wa yìí, ọ̀pọ̀ nǹkan ti bẹ̀rẹ̀ sí í pa run 4 00:00:11,171 --> 00:00:13,612 Afẹ́fẹ́ àti àyíká wa ń bà jẹ́ 5 00:00:14,022 --> 00:00:18,217 Àwọn ọmọdé bíi tèmi pa ẹ̀kọ́ ìwé tì láti wọdé. 6 00:00:18,561 --> 00:00:20,897 A ṣì lè tún ohun tó ti bà jẹ́ ṣe. 7 00:00:20,897 --> 00:00:22,963 Ìwọ náà lè tún un ṣe. 8 00:00:23,372 --> 00:00:26,577 Tá ò bá fẹ́ kí aráyé pa run, a gbọ́dọ̀ jáwọ́ nínú sísun epo rọ̀bì, àmọ́ ìyẹn nìkan ò tó. 9 00:00:27,217 --> 00:00:29,822 Ọ̀pọ̀ àbá ni àwọn èèyàn ti dá, àmọ́ ojútùú kan wà fún wa. 10 00:00:30,112 --> 00:00:32,692 wa 11 00:00:32,692 --> 00:00:35,412 Ẹ jẹ́ kí ọ̀rẹ́ mi George ṣàlàyé. 12 00:00:35,682 --> 00:00:38,112 Ẹ̀rọ ńlá kan wà tó máa ń fa èròjà carbon kúrò nínú afẹ́fẹ́, owó rẹ̀ ò pọ̀, ó sì máa ń tún 13 00:00:38,211 --> 00:00:42,721 ara rẹ̀ ṣe 14 00:00:42,721 --> 00:00:44,418 Òun là ń pè ní ... igi. 15 00:00:44,418 --> 00:00:46,466 Igi jẹ́ ọ̀kan lára ohun tó dá a jù láti fi tún afẹ́fẹ́ ṣe. 16 00:00:46,576 --> 00:00:47,929 Àwọn igi ẹ̀gbà, koríko tó ti kú, igbó ńlá, ilẹ̀ pọ̀tọ̀pọ́tọ́, ìsàlẹ̀ òkun, igbó tí koríko bò, irà, òkìtì iyùn inú òkun 17 00:00:47,929 --> 00:00:48,872 gbogbo wọn ló ń bá wa fa èròjà carbon kúrò nínú afẹ́fẹ́ 18 00:00:48,952 --> 00:00:53,692 Igbó fúnra rẹ̀ ní ohun tó lè bá wa tún afẹ́fẹ́ tó ti bà jẹ́ ṣe. 19 00:00:53,692 --> 00:00:56,502 Tá a bá jẹ́ kí igi àti afẹ́fẹ́ tún àyíká ṣe, àá rí ìyàtọ̀ ńlá. 20 00:00:56,502 --> 00:00:58,772 Ìyẹn dáa, àbí bẹ́ẹ̀kọ́? 21 00:00:58,772 --> 00:01:02,692 Kí ìyẹn tó lè ṣẹlẹ̀, àfi ká fi epo rọ̀bì sàyẹ̀ rẹ̀ nínú ilẹ̀. 22 00:01:03,212 --> 00:01:07,883 Àmọ́ ohun to yani lẹ́nu ni pé ... a ò ṣe ohun tó yẹ ká ṣe 23 00:01:08,502 --> 00:01:12,325 Owó tí à ń ná lórí ìrànwọ́ fún wíwa epo rọ̀bì fi ìlọ́po ẹgbẹ̀rún ju owó tá a fi ń wá 24 00:01:12,325 --> 00:01:14,012 ojútùú lọ. 25 00:01:14,222 --> 00:01:17,622 Ìdá méjì nínú ọgọ́rùn-ún péré là ń ná 26 00:01:19,702 --> 00:01:21,892 nínú gbogbo owó ìrànwọ́ láti fi wá ojútùú sí afẹ́fẹ́ tó ń bà jẹ́. 27 00:01:21,892 --> 00:01:24,402 28 00:01:25,744 --> 00:01:30,548 Owó ẹ, owó orí ẹ àti èyí tí ò ń fi pa mọ́ wà lára owó yìí. 29 00:01:30,548 --> 00:01:32,842 Ibi tí ọ̀rọ̀ wa ni pé ìsinsìnyí gan-an la nílò igi, afẹ́fẹ́ àti àyíká wa jù 30 00:01:32,842 --> 00:01:35,377 àmọ́ ńṣe ni àwọn nǹkan yìí ń bà jẹ́ lọ́nà tó yára kánkán 31 00:01:35,377 --> 00:01:39,053 Ó tó igba (200) ẹ̀dá abẹ̀mí tó ń pa run lójoojúmọ́ 32 00:01:39,394 --> 00:01:41,021 Òkìtì yìnyín ńlá tó wà nípẹ̀kun ayé tí fẹ́rẹ̀ẹ́ yọ́ tán 33 00:01:41,021 --> 00:01:43,468 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹranko inú igbó ti kú tán 34 00:01:43,773 --> 00:01:44,958 Ọ̀pọ̀lọ̀pọ ilẹ̀ ló ti bà jẹ́. 35 00:01:44,958 --> 00:01:47,211 Kí ló yẹ ká ṣe? 36 00:01:47,211 --> 00:01:50,094 Kí ni ìwọ lè ṣe? 37 00:01:50,094 --> 00:01:54,228 Kò le rárá ... a ní láti dáàbò ohun tó ń bà jẹ́, ká tún un ṣe, ká sì fowó ṣètìlẹ́yìn. 38 00:01:54,462 --> 00:01:57,050 Dáàbò bò ó. 39 00:01:57,050 --> 00:01:59,029 Iye àwọn igbó tó wà nílẹ̀ olóoru tí à ń gé 40 00:01:59,029 --> 00:02:01,012 láàárín ìṣẹ́jú kan tó ọgbọ̀n (30) pápá bọ́ọ̀lù. 41 00:02:01,012 --> 00:02:02,813 Àwọn igbó yìí ń ṣe wá lóore, ó yẹ ká dáàbò bò wọ́n 42 00:02:02,813 --> 00:02:04,374 Tún un ṣe 43 00:02:04,374 --> 00:02:05,458 Apá tó pọ̀ jù lọ láyé yìí ti bà jẹ́. 44 00:02:05,458 --> 00:02:06,225 Àmọ́ ó lè sọ ara rẹ̀ dọ̀tun 45 00:02:06,225 --> 00:02:07,429 àwa náà lè ṣèrànwọ́ láti sọ àyíka wa di ọ̀tun 46 00:02:07,429 --> 00:02:08,501 47 00:02:08,501 --> 00:02:09,513 Owó. 48 00:02:10,084 --> 00:02:11,198 A ní láti jáwọ́ nínú nínáwó sórí ohun tó ń ba àyíká jẹ́ 49 00:02:11,198 --> 00:02:13,325 ká náwó sórí ohun tó lè tú un ṣe. 50 00:02:13,325 --> 00:02:16,153 kò jù bẹ́ẹ̀ lọ. 51 00:02:16,153 --> 00:02:18,679 Dáàbò bò ó, tún un ṣe, nawo. 52 00:02:18,679 --> 00:02:20,505 A lè ṣe bẹ́ẹ̀ kárí ayé 53 00:02:20,505 --> 00:02:21,878 Ọ̀pọ̀ èèyàn ti ń lo igi, afẹ́fẹ́, àti àyíká láti wá ojútùú sọ́rọ̀ yìí 54 00:02:21,878 --> 00:02:24,581 Gbogbo wa la gbọ́dọ̀ pawọ́ pọ̀ ṣe é. 55 00:02:24,581 --> 00:02:26,581 Ìwọ náà lè kópa ńbẹ̀. 56 00:02:26,581 --> 00:02:30,042 Dìbò fún àwọn tó ń gbèjà àyíká wa. 57 00:02:31,051 --> 00:02:31,881 Pín fídíò yìí kiri. 58 00:02:32,702 --> 00:02:36,172 Sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀. 59 00:02:36,172 --> 00:02:38,412 Kárí ayé, àwọn èèyàn tí ò fẹ́ kí àyíká wa bà jẹ́ ń wọ́de lórí ọ̀rọ̀ yìí. 60 00:02:39,112 --> 00:02:40,756 Tẹ̀ lé wọn! 61 00:02:40,756 --> 00:02:42,018 Kò sóhun tó gbé. 62 00:02:42,018 --> 00:02:43,044 Ohun tó o bá ṣe ò gbé.