Return to Video

MasterFirefoxOS.com: Camera & Gallery

  • 0:07 - 0:14
    Mímú, ìfipamọ́ àti pípín àwọn fọ́tò àti f́idíò, kòle rọrùn ju lílo Firefox OS kámẹ́rà àti àwọn gbàgede ìṣafilọ́lẹ̀.
  • 0:14 - 0:17
    HDR jẹ́kí àwọn oníbárà rẹ ya àwọn àwòrán tí ó rẹwà
  • 0:18 - 0:22
    wọ́n sì le lo ìlo àkókò láti ya àwòrán wọn àti ti àwọn ọ̀rẹ́.
  • 0:23 - 0:27
    Gbogbo àwọn fọ́tò wọn hàn ni ́aládàṣe ní gbàgede fún ìṣawarí àti ìṣàtúnṣe.
  • 0:30 - 0:33
    Wọ́n lè dán àwọn asẹ́ àrà wò
  • 0:39 - 0:40
    ṣèréjẹ àwọn fọ́tò wọn
  • 0:46 - 0:49
    yí àwọn ààtò ìrí
  • 0:54 - 0:56
    àti àwọn ọ̀pọ̀ ọ̀nà láti pín àwọn fọ́tò wọn,
  • 0:56 - 1:01
    gbogbo àbùdá kámẹ́rà àti gbàgede fọ́tò ni yóò mú gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ àti mọ̀lẹ̀bí rẹ́rìn.
Title:
MasterFirefoxOS.com: Camera & Gallery
Description:

more » « less
Video Language:
English
Duration:
01:04

Yoruba subtitles

Revisions